Story Behind The Song
WE MI NIN'EJE RE JESU:
MO KO ORIN YI NIGBATI OKU OLA TI AO BAPTIST MI (TI AO SE IRIBOMI FUN MI)
Song Description
WE MI NIN'EJE RE JESU
PATAKI EJE JESU TI TA SILE LORI OKE KALFARI
Song Length |
9:10 |
Genre |
Unique - Gospel, World - African |
Tempo |
Slow (71 - 90) |
Lead Vocal |
Mixed Vocals |
Mood |
Composed, Exultant |
Subject |
God, Healing |
Era |
2000 and later |
| |
Lyrics
WE MI NIN'EJE RE JESU mo ko orin yi nigbati oku ola ti ao Baptist mi
1/2/06 5:08pm+ 4:16:06 10.22
Beat:- Dun Ko Ta Ko Dun Dun Ko Tan Koo
CASIOlK70s 13 SOFT ROCK2 @105******
CASIOlK70s 42 FOLKLORE@105
CASIOlK70s 43 RUMBACAT@105**
Lead/Back:-
1. Eje Jesu Tonsan Fun Mi Ni Kalfari
Oti Wemi, Mo Si Ye
Leader:- Wemi Jesu Mi O
Chorus:-
We Mi Nin'eje Re Jesu Wemi Nin'eje Re
We Mi Nin'eje Re Jesu Wemi Nin'eje Re
We Mi Nin'eje Re Jesu Wemi Nin'eje Re
Emi Yo-- Si Di Mimo2x
2.Lead:- Apata Aiyeraiye Odi Abo Mi Ninu Iji
Jeki Eje Mimo Ati Ogbe Ara Re.
Se Iwosan Mi Ki O Wemi Mo Toto
Emi Yo Si Di Mimo
Haleluyah
Chr:-
3.Lead:- Kristi Eni Mimo Oluwa Olufe Mi
Sigi Bo Okan Mi Se Iwosan Ara Mi
Jeki Omi On Eje, Ton San Lati Iha Re
Wo Alebu Aiye Mi
Haleluyah
Chr:-
4.Lead:- Fimi Sinu Ibu Ifere Je Kemi Roju Re
Nigba Tore Ati Ebi Mi Komi Sile
Fun Mi Ni Emi Iye, Ifere Ailegbe,
Emi Yo Sin O Dopin
Haleluyah
Chr:-
5.Lead:Apata 'yeraye Jowo Sebi Isadi Mi
Nigba Tawon Ota N-le Mi Lati Pami
Ki Agbara Nla; Ati Emi Mimo Re
Se ibi: Aabo mi
Haleluyah
Chr:-
6.Lead:Eje Jesu Tonsan FunMi Ni Kalfari
Oti Wemi, Mo Si Ye
Leader:- Wemi Jesu Mi O
Chr:- We Mi Nin'eje Re
7.Lead:- Kristi Eni Mimo Oluwa Olufe Mi
Sigi Bo Okan Mi Se Iwosan Ara Mi
Jeki Omi On Eje, Ton San Lati Iha Re
Wo Alebu Aiye Mi
Haleluyah
Chr:-
8.Lead:- Apata 'yeraiye Jowo Sebi Isadi Mi
Nigba Tawon Ota N-le Mi Lati Pami
Ki Agbara Nla; Ati Emi Mimo Re
Se Ibi aabo Mi
Haleluyah
Chr:-
9. Lead:- Se b'eje Jesu lon gbani la
All:-We Mi Nin'eje Re Jesu Wemi Nin'eje Re-
Emi Yo-- Si Di Mimo
Lead:- Se b'eje Jesu lon woni san
All:-We Mi Nin'eje.....
Lead:- Apata ayeraye odi abo wa ninu iji
All:-We Mi Nin'eje.....
Lead:- Eje mimo eje jesu
All:-We Mi Nin'eje.....
Lead:- Eje ewure ko ni gbani la
All:-We Mi Nin'eje
Lead:- Eje Aguntan koni gbani la
All:-We Mi Nin'eje.....
Lead:- Se b'eje Jesu lon gbani la
All:-We Mi Nin'eje.....
Lead:- Se b'eje Jesu lon woni san
All:-We Mi Nin'eje.....
Lead:- Agbara eje ton gbani la
All:-We Mi Nin'eje.....
Lead:- Agbara eje ton woni san
All:-We Mi Nin'eje.....
Lead:- Apata ayeraye odi abo wa ninu iji
All:-We Mi Nin'eje.....
Lead:- Se b'eje Jesu lon gbani la
All:-We Mi Nin'eje ..
Lead:- Se b'eje Jesu lon woni san
All:-We Mi Nin'eje.....
Lead:- Jowo wemi mo
All:-We Mi Nin'eje.....
Lead:- Jowo wemi mio
All:-We Mi Nin'eje.....
Lead:- Se beje jesu lon gbani la
All:-We Mi Nin'eje.....
Lead:- Se beje jesu lon Woni san
All:-We Mi Nin'eje.....
Chorus:-
We Mi Nin'eje Re Jesu Wemi Nin'eje Re
We Mi Nin'eje Re Jesu Wemi Nin'eje Re
We Mi Nin'eje Re Jesu Wemi Nin'eje Re
Emi Yo-- Si Di Mimo2x
Lead:- Apata 'yeraiye Jowo Sebi Isadi Mi
Nigba Tawon Ota N-le Mi Lati Pami
Ki Agbara Nla; Ati Emi Mimo Re
Se Ibi aabo Mi
Haleluyah
Chr:-
Copyright © 2009 Joseph Awoyemi. All rights reserved.